SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
DAHUN GBOGBO IBEERE
1. Fa ila sabe faweli ( T, A, )
2. Fa ila sabe Oro ti o ni iro faweli ‘en ‘ ( Okan , iyen )
3. Fa ila sabe Oro ti o ni iro faweli ‘in’ ( eyin , eran )
4. Ki ni oruko nnkan yi ni Yoruba?
Aga – (chair , Cup)
Tabili – (Bucket , Table)
5. Ko Oro ti o bere pelu leta wonyi:
A-______________________ E_______________________
6. Fa ila sabe ege Oro meji
Atupa. Abo
Ile-iwe Ewa
Epa Mi